1. Kro 19:19 YCE

19 Nigbati awọn iranṣẹ Hadareseri ri pe a le wọn niwaju Israeli, nwọn ba Dafidi làja, nwọn si nsìn i: bẹ̃ni awọn ara Siria kò jẹ ràn awọn ọmọ Ammoni lọwọ mọ.

Ka pipe ipin 1. Kro 19

Wo 1. Kro 19:19 ni o tọ