1. Kro 24:2 YCE

2 Ṣugbọn Nadabu ati Abihu kú ṣaju baba wọn, nwọn kò si li ọmọ: nitorina ni Eleasari ati Itamari fi ṣiṣẹ alufa.

Ka pipe ipin 1. Kro 24

Wo 1. Kro 24:2 ni o tọ