Jóòbù 1:1 BMY

1 Ọkùnrin kan wà ní ilẹ̀ Húsì, orúkọ ẹni tí í jẹ́ Jóòbù; ọkùnrin náà sì ṣe olóòótọ́, ó dúró ṣinṣin, ẹni tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run, tí ó kórìíra ìwà búburú,

Ka pipe ipin Jóòbù 1

Wo Jóòbù 1:1 ni o tọ