Àìsáyà 10:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n, èyí kì í ṣe ohun tí ó fẹ́ ṣe,èyí kọ́ ni ohun tí ó ní lọ́kàn;èrò rẹ̀ ni láti parun,láti fi òpin sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 10

Wo Àìsáyà 10:7 ni o tọ