Àìsáyà 11:16 BMY

16 Ọ̀nà gidi yóò wà fún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kùtí ó kù sílẹ̀ ní Ásíríà,gẹ́gẹ́ bí ó ti wà fún Ísírẹ́lìnígbà tí wọ́n gòkè láti Éjíbítì wá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:16 ni o tọ