Àìsáyà 11:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n pẹ̀lú òdodo ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní,pẹ̀lú òtítọ́ ni yóò ṣe ìpinnufún àwọn aláìní ayé.Òun yóò lu ayé pẹ̀lú ọ̀pá tí ó wà ní ẹnu rẹ̀,pẹ̀lú ooru ẹnu rẹ̀ ni yóò pa àwọn ìkà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:4 ni o tọ