Àìsáyà 12:2 BMY

2 Nítòótọ́ Ọlọ́run ni ìgbàlà mi,Èmi yóò gbẹ́kẹ̀lé e èmi kì yóò bẹ̀rù. Olúwa, Olúwa náà ni agbára à mi àti orin ìn mi,òun ti di ìgbàlà mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 12

Wo Àìsáyà 12:2 ni o tọ