Àìsáyà 12:6 BMY

6 Kígbe ṣókè kí o sì kọrin fún ayọ̀, ẹ̀yin ènìyàn Ṣíhónì,nítorí títóbi ni ẹni mímọ́ kanṣoṣoti Ísírẹ́lì láàrin yín.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 12

Wo Àìsáyà 12:6 ni o tọ