Àìsáyà 13:13 BMY

13 Nítorí náà èmi yóò jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó wárìrì;ayé yóò sì mì tìtì ní ibùjókòó rẹ̀láti ọwọ́ ìbínú Olúwa àwọn ọmọ-ogun,ní ọjọ́ ìbínú gbígbóná an rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:13 ni o tọ