Àìsáyà 13:20 BMY

20 A kì yóò sì gbé ibẹ̀ mọ́ tàbí kí á gbé inú rẹ̀ láti ìrandíran;Árábù kan yóò fi àgọ́ rẹ lélẹ̀ níbẹ̀,Olùsọ́ àgùntàn kan kì yóò kó ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:20 ni o tọ