Àìsáyà 13:4 BMY

4 Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè,gẹ́gẹ́ bí i ti ogunlọ́gọ̀ ènìyànGbọ́, ìdàrúdàpọ̀ láàrin àwọn ìjọba,gẹ́gẹ́ bí i ti ìkórajọ àwọn orílẹ̀ èdè! Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti kó ogun rẹ̀ jọàwọn jagunjagun fún ogun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:4 ni o tọ