Àìsáyà 13:6 BMY

6 Pohùnréré, nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́tòsí,yóò sì wá gẹ́gẹ́ bí ìparun láti ọ̀dọ̀ Alágbára jùlọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:6 ni o tọ