Àìsáyà 13:9 BMY

9 Kíyèsí i, ọjọ́ Olúwa ń bọ̀ọjọ́ búburú, pẹ̀lú ìbínúàti ìrunú gbígbóná—láti sọ ilẹ̀ náà dahoroàti láti pa àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ inú un rẹ̀ run.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:9 ni o tọ