10 Gbogbo wọn yóò dáhùn,wọn yóò wí fún ọ wí pé,“Ìwọ pẹ̀lú ti di aláìlera, gẹ́gẹ́ bí àwa pẹ̀lúìwọ náà ti dàbí wa.”
Ka pipe ipin Àìsáyà 14
Wo Àìsáyà 14:10 ni o tọ