Àìsáyà 14:22 BMY

22 “Èmi yóò dìde ṣókè sí wọn,”ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.“Èmi yóò ké orúkọ rẹ̀ kúrò ní Bábílónì àti àwọn tí ó sálà,àwọn ọmọ àti ìran rẹ̀,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 14

Wo Àìsáyà 14:22 ni o tọ