Àìsáyà 14:31 BMY

31 Kígbe, Ìwọ ẹnu ọ̀nà! Pariwo, Ìwọ ìlú!Yọ́ kúrò, gbogbo ẹ̀yin Fílístínì!Kurukuru èéfín kan ti Àríwá wá,kò sì sí amóríbọ́ kan nínú ẹgbẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 14

Wo Àìsáyà 14:31 ni o tọ