Àìsáyà 15:3 BMY

3 Wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀ ní ojú òpópónà,ní àwọn òrùlé àti àwọn gbàgede àkójọwọ́n pohùnréré,Wọ́n dọ̀bálẹ̀ pẹ̀lú ẹkún.

Ka pipe ipin Àìsáyà 15

Wo Àìsáyà 15:3 ni o tọ