Àìsáyà 17:14 BMY

14 Ní ihà, ìpayà òjijì!Kí ó tó di òwúrọ̀, a ò rí wọn mọ́!Èyí ni ìpín àwọn tí ó jí wa lẹ́rù,àti ìpín àwọn tí ó fi ogun kó wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:14 ni o tọ