Àìsáyà 17:2 BMY

2 Àwọn ìlú Áróérì ni a ó kọ̀ sílẹ̀fún àwọn agbo ẹran tí yóò máa sùn ṣíbẹ̀,láìsí ẹni tí yóò dẹ́rùbà wọ́n.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:2 ni o tọ