Àìsáyà 17:5 BMY

5 Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkóórè kó àwọnirúgbìn tí ó dúró jọtí ó sì ń kórè irúgbìn pẹ̀lú apá rẹ̀—àti gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí ènìyàn pa ọkà ní àfonífojì ti Réfémù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:5 ni o tọ