Àìsáyà 19:12 BMY

12 Níbo ni àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn rẹ wà báyìí?Jẹ́ kí wọn fi hàn ọ́ kí wọn sì sọ ọ́ di mímọ̀ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogunti pinnu lórí Éjíbítì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:12 ni o tọ