Àìsáyà 19:22 BMY

22 Olúwa yóò fi àjàkálẹ̀-àrùn kan bá Éjíbítì jà; yóò bá wọn jà yóò sì tún wò wọ́n sàn. Wọn yóò yípadà sí Olúwa, Òun yóò sì gbọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn yóò sì wò wọ́n sàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:22 ni o tọ