Àìsáyà 2:20 BMY

20 Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò má a sọàwọn ère fàdákà àti ère wúràtí wọ́n ti yá fún bíbọsí èkúté àti àwọn àdán,

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:20 ni o tọ