Àìsáyà 2:7 BMY

7 Ilẹ̀ wọ́n kún fún fàdákà àti wúràìṣúra wọn kò sì ní òpin.Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ẹṣin,kẹ̀kẹ́ ogun wọn kò sì lópin.

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:7 ni o tọ