Àìsáyà 20:3 BMY

3 Lẹ́yìn náà ni Olúwa wí pé, “Gẹ́gẹ́ bí Ìránṣẹ́ mi Àìsáyà ti lọ káàkiri ní ìhòòhò àti láì wọ bàtà fún ọdún mẹ́ta, gẹ́gẹ́ bí àmì àti àpẹẹrẹ sí Éjíbítì àti Kúṣì,

Ka pipe ipin Àìsáyà 20

Wo Àìsáyà 20:3 ni o tọ