Àìsáyà 21:1 BMY

1 Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan ihà lẹ́bàá òkun:Gẹ́gẹ́ bí ìjì líle ti í jà kọjá ní ilẹ̀ ní gúṣù,akógunjàlú kan wá láti ihà,láti ilẹ̀ ìpayà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 21

Wo Àìsáyà 21:1 ni o tọ