Àìsáyà 22:23 BMY

23 Èmi yóò sì kàn án mọ́lẹ̀ bí èèkàn tí ó dúró gírígírí ní àyèe rẹ̀; òun yóò sì jẹ́ ibùjókòó ọlá fún ilé baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 22

Wo Àìsáyà 22:23 ni o tọ