Àìsáyà 23:3 BMY

3 Láti orí àwọn omi ńláni irúgbìn oníhóró ti ilẹ̀ Ṣíhórì ti wáìkóórè ti Náì ni owóòná Tírè,òun sì ti di ibùjókòó ọjà fúnàwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 23

Wo Àìsáyà 23:3 ni o tọ