Àìsáyà 24:4 BMY

4 Ilẹ̀ ayé ti gbẹ ó sì ṣá,ayé ń ṣòjòjò, àárẹ̀ mú un,àwọn ẹni gíga ilẹ̀ ayé wà nínú ìpọ́njú

Ka pipe ipin Àìsáyà 24

Wo Àìsáyà 24:4 ni o tọ