Àìsáyà 25:11 BMY

11 Wọn yóò na ọwọ́ọ wọn jáde nínú un rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí òmùwẹ̀ tí ń na ọwọ́ọ rẹ̀jáde láti lúwẹ̀ẹ́.Ọlọ́run yóò mú ìgbéraga wọn wálẹ̀bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìṣeféfé wà ọwọ́ ọ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:11 ni o tọ