Àìsáyà 26:15 BMY

15 Ìwọ ti mú orílẹ̀ èdè gbòòrò, Olúwa;ìwọ ti mú orílẹ̀ èdè bí sí i.Ìwọ ti gba ògo fún araàrẹ;ìwọ ti sún gbogbo àwọn ààlà ilẹ̀ ṣẹ́yìn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:15 ni o tọ