Àìsáyà 26:18 BMY

18 Àwa wà nínú oyún, a wà nínú ìroraṣùgbọ́n, afẹ́fẹ́ ni a bí lọ́mọ.Àwa kò mú ìgbàlà wá sí ilẹ̀ ayé;àwa kọ́ ni a bí àwọn ènìyàn tí ó wà láyé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:18 ni o tọ