26 Ọlọ́run rẹ̀ tọ́ ọ sọ́nàó sì kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́ ní ọ̀nà tótọ́.
27 A kì í fi òòlù pa káráwétàbí kẹ̀kẹ́-ẹrù là á fi yí kúmínì mọ́lẹ̀;ọ̀pá ni a fi ń lu káráwé,àti kúmínì pẹ̀lú igi.
28 A gbọdọ̀ lọ hóró kí a tó ṣe àkàrà;bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì í máa pa á lọ títí láé.Bí ó tilẹ̀ yí ẹṣẹ̀ kẹ̀kẹ́ ìpakà a rẹ̀ lóríi rẹ̀,àwọn ẹṣin rẹ̀ kò le lọ̀ ọ́.
29 Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,oníyanu ní ìmọ̀ràn àti ológo ní ọgbọ́n.