Àìsáyà 28:5 BMY

5 Ní ọjọ́ náà Olúwa àwọn ọmọ-ogunyóò jẹ́ adé tí ó lógo,Òdòdó tí ó lẹ́wàfún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:5 ni o tọ