Àìsáyà 3:14 BMY

14 Olúwa dojú ẹjọ́ kọàwọn alàgbà àti àwọn olórí àwọn ènìyàn rẹ̀.“Ẹyin ni ẹ ti run ọgbà àjàrà mi,ogún àwọn tálákà ń bẹ̀ nínú ilé yín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 3

Wo Àìsáyà 3:14 ni o tọ