Àìsáyà 3:9 BMY

9 Ìwò ojú wọn ń jẹ́rìí lòdì sí wọn,wọ́n ń polongo ẹ̀ṣẹ̀ wọn bí i Sódómù;wọn ò fi pamọ́!Ègbé ni fún wọn!Wọ́n ti mú ìparun wá sórí ara wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 3

Wo Àìsáyà 3:9 ni o tọ