Àìsáyà 30:21 BMY

21 Bí o bá yí sápá ọ̀tún tàbí apá òsi, etí rẹ yóò máa gbọ́ ohùn kan lẹ́yìn rẹ, wí pé, “Ọ̀nà nìyìí, máa rìn nínú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:21 ni o tọ