Àìsáyà 30:32 BMY

32 Ẹgba kọ̀ọ̀kan tí Olúwa bá gbé lé wọnpẹ̀lú ọ̀pá ìjẹníyà rẹ̀yóò jẹ́ ti ìlù tamborínì àti ti hápù,gẹ́gẹ́ bí ó ti ń bá wọn jà lójú ogunpẹ̀lú ẹ̀sẹ́ láti apá rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:32 ni o tọ