Àìsáyà 31:9 BMY

9 Ibi gíga wọn ni yóò wó lulẹ̀ nítorí ìpayà;nípa ìrísí agbára ogun wọn, àwọnọ̀gágun wọn yóò wárìrì,”ni Olúwa wí,ẹni tí iná rẹ̀ ń bẹ ní Ṣíhónì,ẹni tí ìléru rẹ̀ wà ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31

Wo Àìsáyà 31:9 ni o tọ