Àìsáyà 32:17 BMY

17 Èṣo òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà;àbájáde òdodo yóò sì jẹ́ ìdákẹ́jẹ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé títí láé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:17 ni o tọ