Àìsáyà 32:2 BMY

2 Ẹnì kọ̀ọ̀kan yóò dàbí ìdáàbòbò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́àti ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì,gẹ́gẹ́ bí odò omi nínú aṣálẹ̀àti òjìji àpáta ńlá ní ilẹ̀ òrùngbẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:2 ni o tọ