Àìsáyà 32:5 BMY

5 A kò ní pe òmùgọ̀ ní bọ̀rọ̀kìnní mọ́tàbí kí a fi ọ̀wọ̀ tí ó ga jù fún mọ̀dàrú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:5 ni o tọ