Àìsáyà 32:9 BMY

9 Ẹ̀yin obìnrin tí ẹ ti gba ìtẹ́lọ́rùn gidiẹ dìde kí ẹ tẹ́tí sí mi,ẹ̀yin ọ̀dọ́mọbìnrin tí ọkàn yín ti balẹ̀,ẹ gbọ́ ohun tí mo fẹ́ sọ!

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:9 ni o tọ