Àìsáyà 33:18 BMY

18 Nínú èrò rẹ ìwọ yóò rántí ẹ̀rù rẹ àtẹ̀yìnwá:“Níbo ni ọ̀gá àgbà náà wà?Níbo ni ẹni tí ń gba owó òde wà?Níbo ni òṣìṣẹ́ ti ó ń mójú tó ilé-ìṣọ́ wà?”

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:18 ni o tọ