Àìsáyà 33:22 BMY

22 Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa, Olúwa ni olófin wa, Olúwa òun ni ọba wa;òun ni ẹni tí yóò gbà wá là.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:22 ni o tọ