Àìsáyà 34:14 BMY

14 Àwọn ẹran ijùàti àwọn ọ̀wàwà ni yóò pàdé,àti sátírè kan yóò máa kọ sí èkejìí rẹ̀,iwin yóò máa gbé ibẹ̀ pẹ̀lú,yóò sì rí ibi isinmi fún ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:14 ni o tọ