Àìsáyà 34:6 BMY

6 Idà Olúwa kún fún ẹ̀jẹ̀a mú un ṣanra fún ọ̀rá,àti fún ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-agùtàn àti ewurẹ,fún ọ̀rá iwe àgbò—nítorí Olúwa ni ìrúbọ kan ní Bósírà,àti ìpakúpa ńlá kan ní ilẹ̀ Édómù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:6 ni o tọ