Àìsáyà 36:13 BMY

13 Lẹ́yìn náà ni ọ̀gágun náà dìde tí ó sì ké sítà ní èdè Hébérù pé, “Ẹ gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọba ńlá, ọba Ásíríà!

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:13 ni o tọ