Àìsáyà 36:15 BMY

15 Ẹ má ṣe jẹ́ kí Heṣekáyà rọ̀ yín láti gbẹ́kẹ̀lé Olúwa nígbà tí ó sọ pé, ‘Olúwa yóò kúkú gbà wá; a kì yóò fi ìlú lé ọba Ásíríà lọ́wọ́.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:15 ni o tọ