Àìsáyà 36:19 BMY

19 Níbo ni àwọn òrìṣà Hámátì àti Ápádì ha wà? Níbo ni àwọn òrìṣà Ṣépáfírámù ha wà? Ǹjẹ́ wọn ti já Ṣamáríà gbà kúrò lọ́wọ́ mi bí?

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:19 ni o tọ